Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a ÀKÍYÈSÍ: Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kò pọn dandan kẹ́ ẹ jíròrò apá tá a pè ní “Ṣèwádìí” nígbà ìkẹ́kọ̀ọ́, síbẹ̀ rí i pé o ka àwọn ìtẹ̀jáde tá a tọ́ka sí, kó o sì wo àwọn fídíò tó wà níbẹ̀ tó o bá ń múra sílẹ̀. Ìyẹn á jẹ́ kó o mọ ohun tá wọ akẹ́kọ̀ọ́ rẹ lọ́kàn àti bó o ṣe lè ràn án lọ́wọ́. Ìwé yìí tó wà lórí ẹ̀rọ ní ìlujá sáwọn fídíò àtàwọn ìtẹ̀jáde tá a tọ́ka sí.