Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ǹjẹ́ o ti kojú ìṣòro tó mú kí nǹkan tojú sú ẹ tàbí tó mú kó o ronú pé o ò já mọ́ nǹkan kan? Tó bá rí bẹ́ẹ̀, àpilẹ̀kọ yìí máa rán ẹ létí pé Jèhófà mọyì rẹ gan-an, o sì ṣeyebíye lójú rẹ̀. Àá tún jíròrò bó o ṣe lè máa fojú tó tọ́ wo ara rẹ láìka ìṣòro yòówù tó o ní sí.