Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àtìgbà Pẹ́ńtíkọ́sì ọdún 33 Sànmánì Kristẹni ni Jèhófà ti ń fún àwọn Kristẹni kan ní ìrètí kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀ pé wọ́n máa ṣàkóso pẹ̀lú Ọmọ òun lọ́run. Àmọ́ báwo làwọn Kristẹni yẹn ṣe mọ̀ pé àwọn ní àǹfààní àgbàyanu yìí? Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ tí Jèhófà bá yan ẹnì kan? Àpilẹ̀kọ yìí máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí. A gbé àpilẹ̀kọ yìí ka àpilẹ̀kọ kan tó jáde nínú Ilé Ìṣọ́ January 2016.