Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Èdìdì. Èyí kì í ṣe èdìdì ìkẹyìn. Ó dìgbà tó bá kù díẹ̀ kí àwọn ẹni àmì òróró kú tí wọ́n sì jẹ́ olóòótọ́ tàbí tó bá kù díẹ̀ kí “ìpọ́njú ńlá” bẹ̀rẹ̀ ni Jèhófà máa tó fún wọn ní èdìdì ìkẹyìn.—Éfé. 4:30; Ìfi. 7:2-4; wo “Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé” nínú Ilé Ìṣọ́ April 2016 lédè Gẹ̀ẹ́sì.