Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ìṣe 2:33 fi hàn pé ipasẹ̀ Jésù ni àwọn ẹni àmì òróró fi rí ẹ̀mí mímọ́ gbà, ó ṣe kedere pé Jèhófà ló yàn wọ́n.