Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A sábà máa ń pe Jèhófà ní Ẹlẹ́dàá wa àti Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run. Bó ṣe rí nìyẹn lóòótọ́, àmọ́ ọ̀pọ̀ ìdí ló wà tó fi yẹ ká gbà pé ó jẹ́ Baba wa àti pé ó nífẹ̀ẹ́ wa gan-an. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ìdí tá a fi sọ bẹ́ẹ̀. A tún máa rí ẹ̀rí táá mú kó dá wa lójú pé Jèhófà ò ní fi wá sílẹ̀ láé.