Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Inú ètò tí àlàáfíà ti jọba la wà. Àmọ́ tá ò bá ṣọ́ra, ìlara lè mú kó ṣòro láti gbádùn àlàáfíà náà. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ àwọn nǹkan tó ń fa ìlara. A sì tún máa jíròrò bá a ṣe lè borí ẹ̀mí burúkú yìí àti bá a ṣe lè jẹ́ kí àlàáfíà jọba.