Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ṣé ó wù ẹ́ pé kó o ṣèrìbọmi? Tó bá rí bẹ́ẹ̀, àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ torí pé ìwọ la dìídì ṣe é fún. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ìbéèrè pàtàkì kan lórí ọ̀rọ̀ ìrìbọmi. Ìdáhùn rẹ sáwọn ìbéèrè yìí máa jẹ́ kó o mọ̀ bóyá lóòótọ́ lo ti ṣe tán láti ṣèrìbọmi.