Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn Sẹ́mítì wá látinú ẹ̀yà Ṣémù tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin mẹ́ta tí Nóà bí. Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Ṣémù ni àwọn ọmọ Élámù, àwọn ará Ásíríà, àwọn ará Kálídíà ìgbàanì, àwọn Hébérù, àwọn ará Síríà àtàwọn ẹ̀yà Arébíà lónírúurú.