Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀWÒRÁN: Ábígẹ́lì lọ bá Dáfídì lásìkò tó yẹ, ó pàrọwà fún un, ìyẹn sì mú kí Dáfídì pèrò dà.