Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé f ÀWÒRÁN: Alàgbà kan ṣe ohun tí kò ní jẹ́ kọ́rọ̀ àṣírí nípa ìjọ ta sí ìyàwó rẹ̀ tàbí àwọn míì létí.