Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Arábìnrin kan ń ṣe ohun táá mú kí àlàáfíà wà láàárín òun àti arábìnrin míì. Lákọ̀ọ́kọ́, arábìnrin kejì kò gbà fún un, àmọ́ arábìnrin àkọ́kọ́ náà kò jẹ́ kó sú òun. Nígbẹ̀yìngbẹ́yín, arábìnrin yẹn gbà, wọ́n sì yanjú ọ̀rọ̀ náà..