Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Bí tọkọtaya kan ṣe ń wàásù láti ilé dé ilé, wọ́n kíyè sí (1) ilé kan tí àyíká rẹ̀ mọ́ tónítóní, tí wọ́n gbin òdòdó sí; (2) ilé kan tí tọkọtaya kan àtàwọn ọmọ wọn kéékèèké ń gbé; (3) ilé kan tí inú àti ìta ẹ̀ dọ̀tí; àti (4) ilé kan táwọn èèyàn ibẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́sìn. Inú ilé wo lo rò pé wàá ti rí ẹni tó máa di ọmọ ẹ̀yìn?