Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b ÀWÒRÁN Ojú Ìwé: Arábìnrin kan ń kọ́ èdè àjèjì kó lè kọ́ àwọn tó kó wá sórílẹ̀-èdè rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.