Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ tó ṣáájú, a jíròrò díẹ̀ lára àwọn ìṣúra tí Jèhófà fún wa tá a lè fojú rí. Ní báyìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìṣúra tá ò lè fojú rí àti bá a ṣe lè fi hàn pé a mọyì wọn. Bákan náà, àá sọ bá a ṣe lè túbọ̀ mọyì Jèhófà tó fún wa láwọn ìṣúra náà.