Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b ÀWÒRÁN Ojú Ìwé: (1) Arábìnrin kan ń wo àwọn nǹkan tí Jèhófà dá, ó sì ń ṣàṣàrò lórí bóun ṣe jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà.