Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àwọn alàgbà lè ṣètò pé kẹ́nì kan jíròrò àwọn orí kan pàtó nínú ìwé ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’ tàbí Sún Mọ́ Jèhófà pẹ̀lú ẹnì kan tó jẹ́ aláìṣiṣẹ́mọ́ àmọ́ tó ti pa dà sínú ìjọ. Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Ìsìn ló máa pinnu ẹni táá darí ìkẹ́kọ̀ọ́ náà.