Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀rọ̀ wo ló ṣe pàtàkì jù lọ sáwa èèyàn àtàwọn áńgẹ́lì? Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì tó bẹ́ẹ̀, báwo ló sì ṣe kàn wá? Tá a bá lóye ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí àtàwọn ìbéèrè míì tó jẹ mọ́ ọn, á jẹ́ kí àjọṣe wa pẹ̀lú Jèhófà túbọ̀ lágbára.