Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Èṣù ba Ọlọ́run lórúkọ jẹ́, ó sọ fún Éfà pé òpùrọ́ ni Ọlọ́run. Àtìgbà yẹn ni Sátánì ti ń tan ẹ̀kọ́ èké kálẹ̀ pé ìkà ni Ọlọ́run àti pé kì í ṣe Òun ló dá àwa èèyàn.