Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn agbéraga àti onímọtara-ẹni-nìkan ló kúnnú ayé lónìí. A gbọ́dọ̀ ṣọ́ra kí wọ́n má bàa kéèràn ràn wá. Torí náà nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá ò ṣe ní máa ro ara wa ju bó ṣe yẹ lọ nínú ìgbéyàwó wa, nínú ètò Ọlọ́run àti nígbà tá a bá ń lo ìkànnì àjọlò.