Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Kó lè rọrùn fún ẹ láti ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́ fáwọn míì, wo ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan” tó jáde nínú Ilé Ìṣọ́ látọdún 2010 sí 2015. Lára àwọn àpilẹ̀kọ yìí ni “Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run?,” “Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀?” àti “Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dá Àwọn Èèyàn Lóró Nínú Iná Ọ̀run Àpáàdì?”