Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ làwa èèyàn Jèhófà ti wá, ojúṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ la sì ní nínú ìjọ. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká mọyì gbogbo àwọn tó wà nínú ìjọ, ká sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.