Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọlọ́gbọ́n, onífẹ̀ẹ́ àti onísùúrù ni Jèhófà Baba wa. Èyí hàn nínú bó ṣe dá gbogbo nǹkan àti nínú ìlérí tó ṣe pé òun máa jí àwọn òkú dìde. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ìbéèrè tó ṣeé ṣe ká ní nípa àjíǹde, a sì máa sọ bá a ṣe lè fi hàn pé a mọyì ìfẹ́, ọgbọ́n àti sùúrù Ọlọ́run.