Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Arákùnrin kan ń sọ fún ọ̀gá ẹ̀ pé àwọn ọjọ́ kan wà láàárín ọ̀sẹ̀ tóun ò ní lè máa ṣe àfikún iṣẹ́. Ó sọ fún un pé àwọn ohun tó jẹ mọ́ ìjọsìn Jèhófà lòun máa ń ṣe láwọn ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ yẹn. Àmọ́ tí wọ́n bá nílò òun lójú méjèèjì láwọn ọjọ́ míì, òun ṣe tán.