Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù pe àwọn apẹja tó mọṣẹ́ wọn níṣẹ́ tí wọ́n sì jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ pé kí wọ́n wá di ọmọ ẹ̀yìn òun. Àwọn tó nírú ànímọ́ yìí ni Jésù ṣì ń pè lónìí pé kí wọ́n wá di apẹja èèyàn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun táwọn akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó ń lọ́ra láti di akéde Ìjọba Ọlọ́run lè ṣe.