Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ tó ṣáájú, a ti jíròrò bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣe lè tẹ̀ síwájú láti di akéde Ìjọba Ọlọ́run. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun mẹ́ta tí gbogbo wa lè ṣe táá jẹ́ ká túbọ̀ pinnu pé àá máa wàásù nìṣó títí dìgbà tí Jèhófà bá sọ pé ó tó, yálà a ṣẹ̀ṣẹ̀ di akéde àbí a ti pẹ́ nínú òtítọ́.