Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Onírúurú ìṣòro làwọn arábìnrin máa ń kojú. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè fara wé Jésù ká sì máa fún àwọn arábìnrin wa níṣìírí. A máa rí bí Jésù ṣe lo àkókò pẹ̀lú àwọn obìnrin, bó ṣe fi hàn pé òun mọyì wọn àti bó ṣe gbèjà wọn.