Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e ÀWÒRÁN: Àwọn ará yìí ń fara wé Jésù. Arákùnrin kan ń bá àwọn arábìnrin kan pààrọ̀ táyà mọ́tò wọn. Arákùnrin míì lọ ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ arábìnrin àgbàlagbà kan. Arákùnrin míì àti ìyàwó ẹ̀ sì lọ sọ́dọ̀ arábìnrin kan àti ọmọbìnrin ẹ̀ kí wọ́n lè jọ ṣe ìjọsìn ìdílé.