Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé The Finished Mystery ni apá keje ìwé Studies in the Scriptures. “ZG” ni ẹ̀dà ẹ̀ tó ní èèpo ẹ̀yìn fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí wọ́n tẹ̀, tí wọ́n sì pè ní The Watch Tower ti March 1, 1918. “Z” yẹn dúró fún Zion’s Watch Tower, nígbà tí “G” dúró fún lẹ́tà keje nínú a,b,d torí pé ìwé yẹn ni apá keje.