Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ohun táwọn òbí Kristẹni fẹ́ ni pé káwọn ọmọ wọn máa fayọ̀ sin Jèhófà bí wọ́n ṣe ń dàgbà. Àwọn ìpinnu wo ló yẹ kí wọ́n ṣe táá jẹ́ káwọn ọmọ wọn lè sin Jèhófà? Àwọn ìpinnu wo ló yẹ káwọn ọmọ ṣe táá jẹ́ kí wọ́n sin Jèhófà jálẹ̀ ìgbésí ayé wọn? A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí.