Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àǹfààní ńlá la ní tá a bá ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì torí pé ṣe là ń jẹ́ kí wọ́n mọ bí Jèhófà ṣe fẹ́ kí wọ́n máa ronú àti bó ṣe yẹ kí wọ́n máa hùwà. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí bá a ṣe lè sunwọ̀n sí i nínú bá a ṣe ń kọ́ni.