Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ ní ìtọ́ni pé kí wọ́n máa sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn, kí wọ́n sì kọ́ wọn láti máa pa gbogbo àṣẹ òun mọ́. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè tẹ̀ lé ìtọ́ni Jésù. Inú Ilé Ìṣọ́ July 1, 2004, ojú ìwé 14-19 la ti mú díẹ̀ lára àwọn àlàyé tá a ṣe nínú àpilẹ̀kọ yìí.