Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó lè ṣòro fáwọn kan lára wa láti ṣe ìyípadà nínú bí wọ́n ṣe ń ronú, bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ àti nínú ìwà wọn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa ṣàlàyé ìdí tó fi yẹ ká ṣe ìyípadà àti bá ò ṣe ní rẹ̀wẹ̀sì bá a ṣe ń ṣe àwọn ìyípadà náà.