Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b ÀWÒRÁN: Jésù lẹni àkọ́kọ́ tí Ọlọ́run jí dìde sọ́run. (Ìṣe 1:9) Lára àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ tí Ọlọ́run máa jí dìde sí ọ̀run ni Tọ́másì, Jémíìsì, Lìdíà, Jòhánù, Màríà àti Pọ́ọ̀lù.