Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jósẹ́fù, Náómì àti Rúùtù, ọmọ Léfì kan àti àpọ́sítélì Pétérù kojú àwọn ìṣòro tó mú kí wọ́n rẹ̀wẹ̀sì. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí bí Jèhófà ṣe tù wọ́n nínú, tó sì fún wọn lókun. A tún máa jíròrò ohun tá a lè rí kọ́ lára wọn, àá sì rí bí Jèhófà ṣe fìfẹ́ ràn wọ́n lọ́wọ́.