Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wa ti ọdún 2021 tẹnu mọ́ ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà bá a ṣe ń kójú àwọn ìṣòro tó ń tánni lókun nísinsìnyí àtèyí tá a máa kojú lọ́jọ́ iwájú. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ọ̀nà tá a lè gbà fi ìmọ̀ràn inú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti ọdún yìí sílò.