Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọjọ́ tí ọkùnrin kan bá gbéyàwó ló di olórí ìdílé. Torí náà, nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun tó túmọ̀ sí láti jẹ́ olórí ìdílé, àá mọ ìdí tí Jèhófà fi ṣe ètò yìí àti ohun táwọn olórí ìdílé lè kọ́ lára Jèhófà àti Jésù. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa jíròrò ohun tí tọkọtaya lè kọ́ lára Jésù àtàwọn àpẹẹrẹ míì nínú Bíbélì. Nínú àpilẹ̀kọ kẹta, a máa sọ̀rọ̀ nípa ipò orí nínú ìjọ.