Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nínú ọ̀pọ̀ fíìmù, eré orí ìtàgé tàbí ìwé, wọ́n sábà máa ń jẹ́ kó dà bíi pé kò sóhun tó burú nínú kí ọkùnrin máa jẹ gàba lé ìyàwó ẹ̀ lórí, kó máa bú u tàbí kó máa lù ú. Nípa bẹ́ẹ̀, ọ̀pọ̀ èèyàn gbà pé kò sóhun tó burú tí ọkọ kan bá ń ṣe bẹ́ẹ̀ sí ìyàwó ẹ̀.