Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ohun tí Jèhófà fẹ́ ni pé kí àwọn aya máa fi ara wọn sábẹ́ ọkọ wọn. Kí nìyẹn túmọ̀ sí? Tó bá di pé ká fi ara wa sábẹ́ àwọn ẹlòmíì, ọ̀pọ̀ nǹkan làwọn tọkọtaya Kristẹni lè kọ́ látinú àpẹẹrẹ Jésù àtàwọn obìnrin tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn.