Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Lọ́nà kan náà, aya kan ń wáyè kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láyè ara ẹ̀ kí ìgbàgbọ́ ẹ̀ lè túbọ̀ lágbára.