Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ipa wo làwọn arábìnrin ń kó nínú ìjọ? Ṣé gbogbo àwọn arákùnrin ló jẹ́ orí fún àwọn arábìnrin? Ṣé àṣẹ kan náà ni àwọn alàgbà àti àwọn olórí ìdílé ní? Àá fi Bíbélì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí.