Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé Jémíìsì sọ onírúurú nǹkan tá a lè ṣe tá a bá ń kojú àdánwò. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò díẹ̀ lára àwọn ìmọ̀ràn tí Jémíìsì fún wa. Àwọn ìmọ̀ràn yìí máa jẹ́ ká lè máa fayọ̀ sin Jèhófà nìṣó bá a tiẹ̀ ń fara da àdánwò.