Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí bí ìfẹ́ tá a ní fún Jèhófà, àwọn ará wa, títí kan àwọn ọ̀tá wa ṣe lè mú ká máa sin Jèhófà nìṣó bí ayé bá tiẹ̀ kórìíra wa. Àá tún rí ìdí tí Jésù fi sọ pé a máa láyọ̀ táwọn èèyàn bá tiẹ̀ kórìíra wa.