Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nígbà tí Jésù ń ṣiṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ lórí ilẹ̀ ayé, àwọn ìgbà kan wà tó máa ń sọ̀rọ̀ tàbí béèrè àwọn ìbéèrè kan kó lè mọ ohun tó wà lọ́kàn àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó mọ ohun tí òun fẹ́ ṣe.—Máàkù 7:24-27; Jòh. 6:1-5; wo Ilé Ìṣọ́, October 15, 2010, ojú ìwé 4 àti 5.