Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Kí nìdí tí Jésù fi kú ikú oró? A máa dáhùn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí, ìyẹn á sì jẹ́ ká túbọ̀ mọyì ìràpadà.