Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó ṣòro fáwọn ará wa kan láti gbà pé Jèhófà lè nífẹ̀ẹ́ àwọn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ìdí tá a fi gbà pé ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ni Jèhófà nífẹ̀ẹ́. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa ohun tá a lè ṣe tá ò fi ní máa ṣiyèméjì pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa.