Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ tó ṣáájú, a jíròrò ìdí mẹ́rin táwọn èèyàn ò fi gbà pé Jésù ni Mèsáyà, a sì tún rídìí tí wọn ò fi fetí sáwa èèyàn Jèhófà lónìí. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rídìí mẹ́rin míì táwọn èèyàn fi ṣe bẹ́ẹ̀. Bákan náà, a máa rí ìdí tí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà ò fi jẹ́ kí ohunkóhun mú àwọn kọsẹ̀.