Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àsìkò tí nǹkan nira là ń gbé báyìí, àmọ́ Jèhófà ń fún wa lókun ká lè fara dà á. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bí Jèhófà ṣe ran àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù àti Tímótì lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa bá iṣẹ́ ìsìn wọn nìṣó láìka ìṣòro tí wọ́n ní sí. Bákan náà, a máa jíròrò nǹkan mẹ́rin tí Jèhófà fún wa ká lè fara da ìṣòro wa lónìí.