Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Nígbà tí Pọ́ọ̀lù wà ní àtìmọ́lé nílùú Róòmù, ó kọ lẹ́tà sáwọn ìjọ, ó sì wàásù fáwọn tó wá kí i.