Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn ibi ẹrọ̀fọ̀ tàbí adágún ni òrépèté ti sábà máa ń hù. Òrépèté lè ga tó mítà márùn-ún, ó sì lè fẹ̀ tó sẹ̀ǹtímítà mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15) nísàlẹ̀.